Náhúmù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa ń jowu, ó sì ń gbẹ̀san. Olúwa ń gbẹ̀san, ó sì kún fún ìbínú Olúwa ń gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá rẹ̀,Ìbínú rẹ̀ kò sì yí padà lórí àwọn ọ̀tá rẹ̀

Náhúmù 1

Náhúmù 1:1-5