Míkà 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ má ṣe ṣọ̀tẹ̀lẹ̀,” ni àwọn Wòlíì wọn wí.“Ẹ má ṣe ṣọtẹ́lẹ̀ nípa nǹkan wọ̀nyí;kí ìtìjú má ṣe le bá wa”

Míkà 2

Míkà 2:1-7