Míkà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ dìde, kí ẹ sì máa lọ!Nítorí èyí kì í ṣe ibi ìsinmi yín,nítorí tí a ti sọ ọ́ di àìmọ́yóò pa yín run,àní ìparun kíkorò.

Míkà 2

Míkà 2:8-12