Míkà 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ègbé ni fún àwọn tí ń gbérò àìṣedéédéétí wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ ibi lórí ibùsùn wọn!Nígbà tí ojúmọ́ bá mọ́, wọn yóò gbé e jádenítorí ó wà ní agbára wọn láti se é.

Míkà 2

Míkà 2:1-3