Míkà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí ọgbẹ́ rẹ̀ jẹ́ aláìlewòtán;ó sì ti wá sí Júdà.Ó sì ti dé ẹnu bodè àwọn ènìyàn mi,àní sí Jérúsálẹ́mù.

Míkà 1

Míkà 1:1-12