Míkà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn òkè ńlá yóò sí yọ́ lábẹ́ rẹ̀,àwọn àfonífojì yóò sì pín yà,bí idà níwájú iná,bí omi tí ó ń ṣàn lọ ni ibi gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́.

Míkà 1

Míkà 1:1-9