Míkà 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kọjá lọ ni ìhòòhò àti ni ìtìjú,ìwọ tí ó ń gbé ni Sáfírì.Àwọn tí ó ń gbé ni Sáánánìkì yóò sì jáde wá.Bétésélì wà nínú ọ̀fọ̀;A ó sì gba ààbò rẹ̀ kúrò lọ́wọ́ yin.

Míkà 1

Míkà 1:4-14