Mátíù 9:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì mọ̀ èrò inú wọn, ó wí pé, “Nítorí kín ni ẹ̀yin ṣe ń ro búburú nínú yín?

Mátíù 9

Mátíù 9:1-7