Mátíù 9:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú wọn sì là; Jésù sì kìlọ̀ fún wọn gidigidi, wí pé, “Kíyèsí i, kí ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnì kan ki o mọ̀ nípa èyí.”

Mátíù 9

Mátíù 9:24-31