Mátíù 8:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù si nà ọwọ́ rẹ̀, ó fi bà á, ó wí pé, “Mo fẹ́, ìwọ di mímọ́”. Lójú kan náà, ẹ̀tẹ̀ rẹ̀ sì mọ́!

Mátíù 8

Mátíù 8:1-6