Mátíù 7:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“È é tí ṣe tí ìwọ fi ń wo èrúnrún igi tí ń bẹ ní ojú arákùnrin rẹ, ṣùgbọ́n ìwọ kò kíyè sí ìtì igi tí ń bẹ ní ojú ara rẹ?

Mátíù 7

Mátíù 7:1-13