Mátíù 7:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí ẹnikẹ́ni tí ó bá gbọ́ ọ̀rọ̀ tèmi wọ̀nyí, tí ó bá sì ṣe wọn, èmi ó fi wé ọlọ́gbọ́n ènìyàn kan, ti ó kọ́ ilé rẹ̀ sí orí àpáta.

Mátíù 7

Mátíù 7:17-29