Mátíù 6:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ìfúnni rẹ má ṣe jẹ́ mímọ̀. Nígbà náà ni Baba rẹ̀, tí ó sì mọ ohun tí ìkọ̀kọ̀ gbogbo, yóò san án fún ọ.

Mátíù 6

Mátíù 6:1-14