Mátíù 6:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni nínú gbogbo yín nípa àníyàn ṣíṣe ti ó lè fi ìṣẹ́jú kan kún ọjọ́ ayé rẹ̀?

Mátíù 6

Mátíù 6:20-31