Mátíù 6:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ojú ni ìmọ́lẹ̀ ara. Bí ojú rẹ bá mọ́lẹ̀ kedere, gbogbo ara rẹ yóò jẹ́ kìkì ìmọ́lẹ̀.

Mátíù 6

Mátíù 6:14-23