Mátíù 6:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó má ṣe hàn sí ènìyàn pé ìwọ ń gbààwẹ̀, bí kò ṣe sìí Baba rẹ, ẹni tí ìwọ kò rí, àti pé, Baba rẹ tí ó rí ohun tí o ṣe ni ìkọ̀kọ̀, yóò san án fún ọ.

Mátíù 6

Mátíù 6:15-20