Mátíù 5:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹ̀yin lè jẹ́ ọmọ Baba yín bi ń bẹ ní ọ̀run. Ó mú kí oòrùn rẹ̀ ràn sára ènìyàn búburú àti ènìyàn rere, ó rọ̀jò fún àwọn olódodo àti fún àwọn aláìṣòdodo.

Mátíù 5

Mátíù 5:44-46