Mátíù 5:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n èmi wí fún yín pé, ‘Ẹ má ṣe tako ẹni ibi. Bí ẹnì kan bá gbá ọ lẹ́rẹ̀kẹ́ ọ̀tún, yí ẹ̀rẹ̀kẹ́ òsì sí olúwa rẹ̀ pẹ̀lú.

Mátíù 5

Mátíù 5:32-44