Mátíù 5:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fi ẹ̀bùn rẹ sílẹ̀ níwájú pẹpẹ. Ìwọ kọ́kọ́ lọ ṣe ìlàjà láàrin ìwọ àti arákùnrin rẹ̀ na. Lẹ́yìn náà, wá kí ó sì fi ẹ̀bùn rẹ sílẹ̀.

Mátíù 5

Mátíù 5:16-34