Mátíù 4:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì rin káàkiri gbogbo Gálílì, ó ń kọ́ni ní sínágọ́gù, ó ń wàásù ìyìn rere ti ìjọba ọ̀run. ó sì ń ṣe ìwòsàn àrùn gbogbo àti àìsàn láàrin gbogbo ènìyàn.

Mátíù 4

Mátíù 4:19-25