Mátíù 3:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni ti ìmúga ìpakà Rẹ̀ ń bẹ ní ọwọ́ rẹ̀, yóò gbá ilẹ̀ ìpakà rẹ̀, yóò kó ọkà rẹ̀ sínú àká, ṣùgbọ́n ìyàngbò ni yóò fi iná àjóòkú sun.”

Mátíù 3

Mátíù 3:7-16