Mátíù 28:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ọjọ́ ọ̀ṣẹ̀, bí ilẹ̀ ti ń mọ́, Máríà Magidalénì àti Màríà kejì lọ sí ibojì.

Mátíù 28

Mátíù 28:1-3