Mátíù 27:65 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pílátù sì pàṣẹ pé, “Ẹ lo àwọn olùṣọ́ yín kí wọn dáàbò bo ibojì náà bí ẹ bá ti fẹ́.”

Mátíù 27

Mátíù 27:61-66