Mátíù 27:63 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sọ fún un pé, “Alàgbà, ẹlẹ́tàn náà wí nígbà kan pé, ‘Lẹ́yìn ọjọ́ kẹta èmi yóò tún jí dìde.’

Mátíù 27

Mátíù 27:55-66