Mátíù 27:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pílátù sì béèrè pé, “Nítorí kí ni? Kí ló ṣe tí ó burú?”Wọ́n kígbe sókè pé, “Kàn án mọ́ àgbélébùú! Kàn án mọ́ àgbélébùú!”

Mátíù 27

Mátíù 27:20-33