Mátíù 27:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó jẹ́ àṣà Baálẹ̀ láti dá ọ̀kan nínú àwọn ẹlẹ́wọ̀n Júù sílẹ̀ lọ́dọọdún, ní àsìkò àjọ̀dún ìrékọjá. Ẹnikẹ́ni tí àwọn ènìyàn bá ti fẹ́ ni.

Mátíù 27

Mátíù 27:14-17