Mátíù 26:67 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n tu itọ́ sí i ní ojú. Wọ́n gbá a lẹ́sẹ̀ẹ́. Àwọn ẹlòmíràn sì gbá a lójú.

Mátíù 26

Mátíù 26:61-75