Mátíù 26:61 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn wí pé, “Ọkùnrin yìí sọ pé, ‘èmi lágbára láti wó tẹ̀ḿpìlì Ọlọ́run lulẹ̀, èmi yóò sì tún un mọ ní ọjọ́ mẹ́ta.’ ”

Mátíù 26

Mátíù 26:60-62