Mátíù 26:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tún fi wọ́n sílẹ̀ nígbà kejì, ó sí gbàdúrà pé, “Baba mi, bí aago yìí kò bá lè ré mi lórí kọjá àfi tí mo bá mu ún, ìfẹ́ tìrẹ ni kí a ṣe.”

Mátíù 26

Mátíù 26:36-49