Mátíù 25:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Níkẹyìn, ọkùnrin tí a fún ní tálẹ́ǹtì kan wá, ó wí pé, ‘Olúwa, mo mọ̀ pé oǹrorò enìyàn ni ìwọ ń ṣe ìwọ ń kórè níbi tí ìwọ kò gbìn sí, ìwọ ń kó jọ níbi tí ìwọ kò ó ká sí.

Mátíù 25

Mátíù 25:20-27