Mátíù 24:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó ṣe rí ní ìgbà ayé Nóà, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni wíwá Ọmọ-Ènìyàn yóò sì rí.

Mátíù 24

Mátíù 24:31-42