Mátíù 24:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́, nígbà tí ẹ̀yin bá sì rí i tí gbogbo nǹkan wọ̀nyí bá ń ṣẹlẹ̀, kí ẹ mọ̀ pé ìpadabọ̀ mi dé tán lẹ́yìn ìlẹ̀kùn.

Mátíù 24

Mátíù 24:24-37