Mátíù 24:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì rán àwọn ańgẹ́lì rẹ̀ jáde pẹ̀lú ohùn ìpè ńlá, wọn yóò sì kó gbogbo àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ láti orígun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ayé àti ọ̀run jọ.

Mátíù 24

Mátíù 24:21-32