Mátíù 23:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n á di ẹrù wúwo tí ó sì ṣòro láti rù, wọ́n a sì gbé e le àwọn ènìyàn léjìká, ṣùgbọ́n àwọn tìkára wọn kò jẹ́ fi ìka wọn kan an.

Mátíù 23

Mátíù 23:2-14