Mátíù 23:38-39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

38. Wò ó, a fi ilé yín sílẹ̀ fún yín ní ahoro.

39. Nítorí èmi sọ èyí fún yín, ẹ̀yin kì yóò rí mi mọ́, títí ẹ̀yin yóò fi sọ pé ‘Olùbùkún ni ẹni tó ń bọ̀ ní orúkọ Olúwa.’ ”

Mátíù 23