Mátíù 23:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pé, ẹni tí ó bá sì fi ọ̀run búra, ó fi ìtẹ́ Ọlọ́run àti ẹni tí ó jókòó lóri rẹ̀ búra.

Mátíù 23

Mátíù 23:13-31