Mátíù 23:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ègbé ni fún yín, ẹ̀yin afójú ti ń fi ọ̀nà han afọ́jú! Tí ó wí pé, ‘Ẹnikẹ́ni tí ó ba fi tẹ́ḿpílì búra kò sí nǹkan kan, ṣùgbọ́n bí ẹnikẹ́ni bá fi wúrà inú tẹ́ḿpílì búra, ó di ajigbèsè.’

Mátíù 23

Mátíù 23:13-25