Mátíù 22:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n wí pé, “Olùkọ́, Mósè wí fún wa pé, bí ọkùnrin kan bá kú ní àìlọ́mọ, kí arákùnrin rẹ̀ sú aya rẹ̀ lópó, kí ó sì bí ọmọ fún un.

Mátíù 22

Mátíù 22:17-31