Mátíù 22:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìjọba ọ̀run dàbí ọba kan ti ó múra àṣè ìgbéyàwó ńlá fún ọmọ rẹ̀ ọkùnrin.

Mátíù 22

Mátíù 22:1-6