Mátíù 21:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níkẹyìn, baálé ilé yìí rán ọmọ rẹ̀ pàápàá sí wọn. Ó wí pé, ‘Wọn yóò bu ọlá fún ọmọ mi.’

Mátíù 21

Mátíù 21:35-43