Mátíù 21:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìdà kejì, bí àwa bá sì sọ pé, ‘Láti ọ̀dọ̀ ènìyàn,’ àwa bẹ̀rù ìjọ ènìyàn, nítorí gbogbo wọ́n ka Johanu sí wòlíì.”

Mátíù 21

Mátíù 21:25-33