Mátíù 21:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Jésù sì ti ń wọ Jerúsálémù, gbogbo ìlú mì tìtì, àwọn ènìyàn bẹ̀rẹ̀ sí í bi ara wọn pé, “Ta nì yìí?”

Mátíù 21

Mátíù 21:9-15