Mátíù 20:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù béèrè pé, “Kí ni ìwọ ń fẹ́?”Ó sì dáhùn pé, “Jẹ́ kí àwọn ọmọ mi méjèèjì jókòó ní apá ọ̀tún àti apá òsì lórí ìtẹ́ ìjọba rẹ?”

Mátíù 20

Mátíù 20:17-28