Mátíù 20:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí ìjọba ọ̀run dàbí ọkùnrin tí ó jẹ́ baálé kan, tí ó jí jáde lọ ní kùtùkùtù òwúrọ̀, tí ó gba àwọn alágbàṣe sínú ọgbà àjàrà rẹ̀.

Mátíù 20

Mátíù 20:1-11