Mátíù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì rán wọn lọ sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù, ó sì wí pé, “Ẹ lọ ṣe ìwádìí fínnífínní ní ti ọmọ náà tí a bí. Lẹ́yìn tí ẹ bá sì rí i, ẹ padà wá sọ fún mi, kí èmi náà le lọ foríbalẹ̀ fún un.”

Mátíù 2

Mátíù 2:5-10