Mátíù 2:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“A gbọ́ ohùn kan ní Rámà,Ohùn réré ẹkún àti ọ̀fọ̀ ńláRákélì ń sọkùn àwọn ọmọ rẹ̀Ó kọ̀ láti gbìpẹ̀nítorí àwọn ọmọ rẹ̀ tí kò sí mọ́.”

Mátíù 2

Mátíù 2:14-19