Mátíù 19:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọdékùnrin náà tún wí pé, “Gbogbo òfin wọ̀nyí ni èmi ti ń pamọ́, kí ni nǹkan mìíràn tí èmi mo ní láti ṣe?”

Mátíù 19

Mátíù 19:12-27