Mátíù 19:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dá a lóhùn pé, “È é ṣe tí ìwọ fi ń béèrè nípa ohun rere lọ́wọ́ mi. Ẹni kan ṣoṣo ni ó wà tí í ṣe Ẹni rere. Bí ìwọ bá fẹ́ dé ibi ìyè, pa àwọn òfin mọ́.”

Mátíù 19

Mátíù 19:8-21