Mátíù 18:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ibínú, olówó rẹ̀ fi í lé àwọn onítúbú lọ́wọ́ láti fi ìyà jẹ ẹ́, títí tí yóò fi san gbogbo gbésè èyí ti ó jẹ ẹ́.

Mátíù 18

Mátíù 18:28-35