Mátíù 18:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà náà ni ọmọ-ọ̀dọ̀ náà wólẹ̀ lórí eékún níwájú rẹ. ‘Ó bẹ̀bẹ̀ pé, mú sùúrù fún mi, èmi yóò sì san gbogbo rẹ̀ fún ọ.’

Mátíù 18

Mátíù 18:25-35